Mimo L’Oluwa by Tope Alabi
Another lovely brand new gospel music from Tope Alabi – Mimo L’Oluwa.
Nigerian talented award winning Christian Gospel music minister, music singer and songwriter, Tope Alabi has released another amazing brand new gospel music which she titled “Mimo L’Oluwa”. And it’s right available here on Gospelhome.com.ng for your free and fast download!
Check Out The Full Lyrics Below;
Mimo Loluwa
Mimo Angeli won mi ke Awon Orun mi ke Mimo Egbageje irawo Mimo Mimo Loluwa Mimo Angeli won mi ke Awon Orun mi ke Mimo Agbagba merinlelogun Lorigun mererin aye o Mimo Atoke atile Mimo Se ni won nke tantan o Mimo Ta ni yo gori Oke oluwa Mimo Tabi tani yo duro nine Mimo Eni to ni owo Mimo, ati aya funfun Mimo o loluwa Mimo o Mimo o Mimo o Mimo o fun fun nene ni Mimo Kabiyesi eledumare Oba Mimo Oba NLA Gbogbo aye e teriba fun Oba adari hurun Oba to ni emi inu eniyan pata Onikokoro aye lowo Adagagodo emi gbogbo eniyan Olukangun orun, ajosun edumare Jigbinigbin, awuwo bi ate ileke Mimo Opa tirin kanle o kan orun Ajosun edumare, minimini ojo to njara o deyan Mimo Orun wawa nigba to padabo sipo Olorun to sosupa dale torutoru Oba toun Soun gbogbo lasiko lasiko Oba to let feyin eni ti, ta le feyin re ti laelae Are NLA, Oga tenikan o bi To bimo Kari aye porogodo Olowori gbogbo aye, orogodigo baba awon eru Mimo Mimo Oniwa funfun, oba adake se in, Tenikan o le se un si Ninu ogo gangan lo ti fohun Ologo to ju Ogo lo ni Mimo. Kabiyo o si, emi o je fi osere, afi eni to be fegba query lido re. Mi o je foju di o Oba ti o se wo loju wo O ti e leti, ai le dibaje ni o Baba NLA Ku Baba mi O le pin yikin Mimo Gbogbo eni to be mi riri Oluwa, e Teri ba Ewa riri fun Oba tite re ki si Ibere at opin, Olorun ajanaku, tin mi gbo kijikiji Mimo Tabubu, tale bu tan, pupo si ni gbogbo ojo Eje ka sale fun Oba rere ta ba mo riri Emi inu awon woli Atobitan, alainiye, popo koja riri Terere koja kika, gungun lailopin Ailetuwo, adaun ro, adaun se, adaun so Oluwa inu awon orun, Oke NLA, arogunmatidi Arabaribiti, aribirabata Ejinkota biko yingirin Ojo foke bi koyegere Oke o le SA, Oke o le he Koseni to le no aditu re, Olodumare Iwo Lodi Iwo lo le tu, Oba NLA gbogbo agbaye loun Teriba fun o baba Agba Gbangba gbangba, jaranjaran, fenfefenfe Iba o iba Iwọ lodi Iwọ lo lè tu, Ọba nla gbogbo àgbáyé lòún tẹriba fún ọ baba Agba Gbángba gbángba, jaranjaran, fenfefenfe Iba o iba… Mímọ L’oluwa Mímọ Angẹli wọn mi ke Mímọ Àwọn Ọrùn wọn mi ke Mímọ Egbaagbeje ìràwọ MímọDownload Below!
What do you think about this song?
We want to hear from you all.
Drop your comments